Yoruba ni arise ni arika, arika ni baba iregun, ohun ti a ba se lonii, o n bọ wa di itan lẹyinwa ọla. Ọpọ ẹda to si ti wa saye ni orukọ wọn wa ninu iwe akọsilẹ manigbagbe, boya fun isẹ rere ti wọn ...